Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection: Illustrative of the new birth
Àwọn ẹsẹ nípa Illustrative of the new birth
Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, wákàtí náà ń bọ̀, ó sì dé tán nísinsin yìí, nígbà tí àwọn òkú yóò gbọ́ ohùn Ọmọ Ọlọ́run, àwọn tí ó bá gbọ́ yóò sì yè.