Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection: Of saints shall be followed by the change of those then alive
Àwọn ẹsẹ nípa Of saints shall be followed by the change of those then alive
Kíyèsi í, ohun ìjìnlẹ̀ ni mo sọ fún un yín, gbogbo wá kì yóò sùn, ṣùgbọ́n gbogbo wá ní a ó paláradà.
Nígbà náà ni a ó gba àwa tí ó sì wà láààyè sókè nínú àwọsánmọ̀ láti ọwọ́ Olúwa. A ó sì wà pẹ̀lú rẹ̀ títí láéláé.