Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Thanksgiving: For the triumph of the gospel
Àwọn ẹsẹ nípa For the triumph of the gospel
Ṣùgbọ́n ọpẹ́ ni fún Ọlọ́run, ẹni tí ń yọ ayọ̀ ìṣẹ́gun lórí wá nígbà gbogbo nínú Kristi, tí a sì ń fi òórùn dídùn ìmọ̀ rẹ̀ hàn nípa wa níbi gbogbo.