Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Thanksgiving: Resolved to offer

2 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Resolved to offer

  1. Títí láéláé, èmi yóò máa yìn ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ Olúwa; èmi yóò sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ.

  2. nítorí ìdí èyí ni kí ọkàn mi máa yìn ọ́, kí o má sì ṣe dákẹ́. Ìwọ Olúwa Ọlọ́run mi, èmi yóò máa fi ọpẹ́ fún ọ títí láé.