Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tents: Sending persons to seek a convenient place for, alluded to
Àwọn ẹsẹ nípa Sending persons to seek a convenient place for, alluded to
tí ń ṣáájú u yín lọ ní gbogbo ọ̀nà yín, nípa fífi iná ṣe amọ̀nà yín ní òru àti ìkùùkuu ní ọ̀sán, láti fi àwọn ibi tí ẹ lè tẹ̀dó sí hàn yín àti àwọn ọ̀nà tí ẹ ó rìn.