Aphek
32.1000, 34.9300 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Aphek
ọba Afeki, ọ̀kan ọba Laṣaroni, ọ̀kan
Ọ̀rọ̀ Samuẹli tọ gbogbo àwọn ọmọ Israẹli wá. Nísinsin yìí àwọn ọmọ Israẹli jáde láti lọ bá àwọn Filistini jà. Àwọn ọmọ Israẹli sì pàgọ́ sí Ebeneseri àti àwọn Filistini ní Afeki.
Àwọn Filistini sì kó gbogbo ogun wọn jọ sí Afeki: Israẹli sì dó ni ibi ìsun omi tí ó wà ní Jesreeli.