Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tema

5 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema.

  2. Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema,

  3. Ẹgbẹ́ oníṣòwò Tema ń wá omi, àwọn oníṣòwò Ṣeba ń dúró dè wọ́n ní ìrètí.

  4. gbé omi wá fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹ; ẹ̀yin tí ó ń gbé Tema, gbé oúnjẹ wá fún àwọn ìsáǹsá.

  5. Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré.