Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tema: 2. A people of Arabia, probably descendant from Tema, Ishmael's son
Àwọn ẹsẹ nípa 2. A people of Arabia, probably descendant from Tema, Ishmael's son
Ẹgbẹ́ oníṣòwò Tema ń wá omi, àwọn oníṣòwò Ṣeba ń dúró dè wọ́n ní ìrètí.
gbé omi wá fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹ; ẹ̀yin tí ó ń gbé Tema, gbé oúnjẹ wá fún àwọn ìsáǹsá.
Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré.