Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Spiritual Peace: We should love

1 ẹsẹ · 53 abala

Àwọn ẹsẹ nípa We should love

  1. Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé: “Àwẹ̀ oṣù kẹrin, karùn-ún, keje, àti tí ẹ̀kẹwàá, yóò jẹ́ ayọ̀ àti dídùn inú, àti àpéjọ àríyá fún ilé Juda; nítorí náà, ẹ fẹ́ òtítọ́ àti àlàáfíà.”