Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Slander: A characteristic of the devil

1 ẹsẹ · 71 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A characteristic of the devil

  1. Mo sì gbọ́ ohùn ńlá ní ọ̀run, wí pè: “Nígbà yìí ni ìgbàlà dé, àti agbára, àti ìjọba Ọlọ́run wá, àti ọlá àti Kristi rẹ̀. Nítorí a tí le olùfisùn àwọn arákùnrin wa jáde, tí o ń fi wọ́n sùn níwájú Ọlọ́run wa lọ́sàn án àti lóru.