Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Slander: Bearing false witness
Àwọn ẹsẹ nípa Bearing false witness
Ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ́rìí èké sí ẹnìkejì rẹ.
Ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ́rìí èké sí ẹnìkejì rẹ.
Àwọn ọmọ-ogun sì béèrè lọ́dọ̀ rẹ̀ pé, “Àti àwa, kí ni àwa ó ṣe?” Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe hùwà ipá sí ẹnikẹ́ni, kí ẹ má sì ṣe ka ẹ̀sùn èké sí ẹnikẹ́ni; kí òwò ọ̀yà yín tó yín.”