Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Silver: Taken in war purified by fire
Àwọn ẹsẹ nípa Taken in war purified by fire
Kìkì i wúrà, fàdákà, idẹ, irin, idẹ àti òjé.
Ohunkóhun tí ó lè la iná ni kí ẹ̀yin ó mú la iná, nígbà náà ni yóò jẹ́ mímọ́. Ṣùgbọ́n ẹ yóò fi omi ìyàsímímọ́ sọ ọ́ di mímọ́. Àti gbogbo ohun tí kò lè la iná kọjá ni kí a mú la inú omi.