Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Silver: Given by the Israelite for making the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Given by the Israelite for making the tabernacle
“Wọ̀nyí ni ọrẹ ti ìwọ yóò gbà ni ọwọ́ wọn: “wúrà, fàdákà àti idẹ;
Àwọn tí ó mú ọrẹ fàdákà tàbí idẹ wá, mú ọrẹ wá fún Olúwa, àti olúkúlùkù ẹni tí ó ní igi ṣittimu fún ipa kankan nínú iṣẹ́ mú un wá.