Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sickness: Exhibits his power in healing

1 ẹsẹ · 47 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Exhibits his power in healing

  1. Ní ọjọ́ kan, bí ó sì ti ń kọ́ni, àwọn Farisi àti àwọn amòfin jókòó pẹ̀lú rẹ̀, àwọn tí ó ti àwọn ìletò Galili gbogbo, àti Judea, àti Jerusalẹmu wá: agbára Olúwa sì ń bẹ pẹ̀lú rẹ̀ láti mú wọn láradá.