Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seraiah: 4. Son of Kenaz

2 ẹsẹ · 7 abala

Wá "Seraiah"

Àwọn ẹsẹ nípa 4. Son of Kenaz

  1. Àwọn ọmọ Kenasi: Otnieli àti Seraiah. Àwọn ọmọ Otnieli: Hatati àti Meonotai.

  2. Meonotai sì ni baba Ofira. Seraiah sì jẹ́ baba Joabu, baba Geharaṣinu. A pè báyìí nítorí àwọn ènìyàn àwọn oníṣọ̀nà ní ìwọ̀n.