Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seraiah: 10. A servant of Zedekiah

2 ẹsẹ · 7 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 10. A servant of Zedekiah

  1. Ọ̀rọ̀ tí Jeremiah wòlíì pàṣẹ fún Seraiah, ọmọ Neriah, ọmọ Maseiah, nígbà tí o ń lọ ni ti Sedekiah, ọba Juda, sí Babeli ní ọdún kẹrin ìjọba rẹ̀. Seraiah yìí sì ní ìjòyè ibùdó.

  2. Jeremiah sì sọ fún Seraiah pé, “Nígbà tí ìwọ bá dé Babeli, kí ìwọ kí ó sì wò, kí ìwọ kí ó sì ka gbogbo ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.