Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Will and Stubbornness: David
Àwọn ẹsẹ nípa David
Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ ọba borí ti Joabu, àti ti àwọn olórí ogun. Joabu àti àwọn olórí ogun sì jáde lọ kúrò níwájú ọba, láti lọ ka àwọn ènìyàn Israẹli.