Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Will and Stubbornness: Refusing to hearken to parents

2 ẹsẹ · 30 abala

Wá "Self-Will and Stubbornness"

Àwọn ẹsẹ nípa Refusing to hearken to parents

  1. Bí ọkùnrin kan bá ní aláìgbọ́ràn tàbí ọlọ̀tẹ̀ ọmọ tí kò gbọ́rọ̀ sí baba àti ìyá rẹ̀ tí kò sì ní í gbà tí wọ́n bá ń bá a wí,

  2. baba àti ìyá rẹ̀ yóò gbá a mú, wọn yóò mu wá fún àwọn àgbàgbà ní ẹnu-bodè ìlú u rẹ̀.