Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sacrifices: At all the feasts

1 ẹsẹ · 55 abala

Àwọn ẹsẹ nípa At all the feasts

  1. Bẹ́ẹ̀ náà ni ní ọjọ́ ayọ̀ yín, ní gbogbo àjọ̀dún tí a yàn àti ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù yín, ni kí ẹ máa fun fèrè lórí ẹbọ sísun àti ọrẹ àlàáfíà yín, wọn yóò sì jẹ́ ìrántí fún yín níwájú Ọlọ́run. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.”