Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness Imputed: The righteousness of God, without the law
Àwọn ẹsẹ nípa The righteousness of God, without the law
Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, a ti fi òdodo Ọlọ́run hàn láìsí òfin, tí a ti ń jẹ́rìí sí nípa òfin àti nípa àwọn wòlíì,