Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness Imputed: Abraham
Àwọn ẹsẹ nípa Abraham
Ìbùkún yìí ha jẹ́ ti àwọn akọlà nìkan, tàbí ti àwọn aláìkọlà pẹ̀lú? Nítorí tí a wí pé, Abrahamu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.
Nítorí náà ni a sì ṣe kà á sí òdodo fún un.
Gẹ́gẹ́ bí Abrahamu “Ó gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.”