Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness Imputed: Christ being made righteousness to us
Àwọn ẹsẹ nípa Christ being made righteousness to us
Nítorí rẹ̀ ni ẹ̀yin ṣe wà nínú Kristi Jesu ẹni ti ó jásí ọgbọ́n fún wa láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run—èyí ń ni, òdodo, ìwà mímọ́ àti ìràpadà wa.