Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness Imputed: Desire to be found in
Àwọn ẹsẹ nípa Desire to be found in
kí a sì lè bá mi nínú rẹ̀, láìní òdodo tí èmi tìkára mi, tí ó ti inú òfin wá, ṣùgbọ́n èyí tí ó ti inú ìgbàgbọ́ wá nínú Kristi, òdodo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run nípasẹ̀ ìgbàgbọ́.