Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ploughing: Of a course of sin

2 ẹsẹ · 17 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Of a course of sin

  1. Àní bí èmi ti rí i pé, àwọn tí ń ṣe ìtulẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀, tí wọ́n sì fún irúgbìn ìwà búburú, wọn a sì ká èso rẹ̀ náà.

  2. Ṣùgbọ́n ẹ tí gbin búburú ẹ si ka ibi, ẹ ti jẹ èso èké nítorí ẹ tí gbẹ́kẹ̀lé agbára yín àti àwọn ọ̀pọ̀ jagunjagun yín,