Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Passover: Prisoner released at, by the Romans

5 ẹsẹ · 14 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Prisoner released at, by the Romans

  1. Ó jẹ́ àṣà gómìnà láti dá ọ̀kan nínú àwọn ẹlẹ́wọ̀n Júù sílẹ̀ lọ́dọọdún, ní àsìkò àjọ̀dún ìrékọjá. Ẹnikẹ́ni tí àwọn ènìyàn bá ti fẹ́ ni.

  2. Ní báyìí, nígbà àjọ, gẹ́gẹ́ bí àṣà, òun a máa dá òǹdè kan sílẹ̀ fún wọn, ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá béèrè fún.

  3. Ǹjẹ́ èmi ó nà án, èmi ó sì fi í sílẹ̀ lọ.”

  4. (For of necessity he must release one unto them at the feast.)

  5. Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ní àṣà kan pé, kí èmi dá ọ̀kan sílẹ̀ fún yín nígbà àjọ ìrékọjá, nítorí náà ẹ ó ha fẹ́ kí èmi dá ọba àwọn Júù sílẹ̀ fún yín bí?”