Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obed: 1. Son of Boaz and grandfather of David

9 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Son of Boaz and grandfather of David

  1. Àwọn obìnrin àdúgbò sì wí pé, “A bí ọmọkùnrin kan fún Naomi.” Wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Obedi. Òun sì ni baba Jese tí í ṣe baba Dafidi.

  2. Èyí ni ìran Peresi: Peresi ni baba Hesroni,

  3. Hesroni ni baba Ramu, Ramu ni baba Amminadabu

  4. Amminadabu ni baba Nahiṣoni, Nahiṣoni ni baba Salmoni,

  5. Salmoni ni baba Boasi, Boasi ni baba Obedi,

  6. Obedi ní baba Jese, Jese ni baba Dafidi.

  7. Boasi baba Obedi àti Obedi baba Jese.

  8. Salmoni ni baba Boasi, Rahabu sí ni ìyá rẹ̀; Boasi ni baba Obedi, Rutu sí ni ìyá rẹ̀; Obedi sì ni baba Jese;

  9. tí í ṣe ọmọ Jese, tí í ṣe ọmọ Obedi, tí í ṣe ọmọ Boasi, tí í ṣe ọmọ Salmoni, tí í ṣe ọmọ Nahiṣoni,