Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Night: Wearisome to the afflicted

2 ẹsẹ · 42 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Wearisome to the afflicted

  1. Bẹ́ẹ̀ ni a mú mi ní ìbànújẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù, òru ìdáni-lágara ni a sì là sílẹ̀ fún mi.

  2. Nígbà ti mo dùbúlẹ̀, èmi wí pé, ‘Nígbà wo ni èmi ó dìde?’ Tí òru yóò sì kọjá, ó sì tó fún mi láti yí síyìn-ín yí sọ́hùn-ún, títí yóò fi di àfẹ̀mọ́júmọ́.