Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Money: Mite

2 ẹsẹ · 40 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Mite

  1. Ṣùgbọ́n obìnrin opó kan wà, ó sì fi ààbọ̀ owó idẹ méjì síbẹ̀, tí ì ṣe ìdá méjì owó-babà kan sínú rẹ̀.

  2. Ó sì rí tálákà opó kan pẹ̀lú, ó ń sọ owó idẹ wẹ́wẹ́ méjì síbẹ̀.