Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Modern Samaria: Had no intercourse or dealings with the Jews

3 ẹsẹ · 23 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Had no intercourse or dealings with the Jews

  1. Ó sì rán àwọn ìránṣẹ́ lọ sí iwájú rẹ̀. Nígbà tí wọ́n sì lọ wọ́n wọ ìletò kan tí í ṣe ti ará Samaria láti pèsè sílẹ̀ dè é.

  2. Wọn kò sì gbà á, nítorí pé ó ń lọ sí Jerusalẹmu.

  3. Obìnrin ará Samaria náà sọ fún un pé, “Júù ni ìwọ, obìnrin ará Samaria ni èmi. Èétirí tí ìwọ ń béèrè ohun mímu lọ́wọ́ mi?” (Nítorí tí àwọn Júù kì í bá àwọn ará Samaria ṣe pọ̀.)