Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ministers: Teach

1 ẹsẹ · 118 abala

Wá "Ministers"

Àwọn ẹsẹ nípa Teach

  1. Àwọn ohun ti ìwọ ti gbọ́ lọ́dọ̀ mi níwájú ẹlẹ́rìí púpọ̀, àwọn náà ni kí ìwọ fi lé àwọn olóòtítọ́ ènìyàn lọ́wọ́, àwọn ti yóò lè máa kọ́ àwọn ẹlòmíràn pẹ̀lú.