Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ministers: Woe to those who do not preach the gospel
Àwọn ẹsẹ nípa Woe to those who do not preach the gospel
Nítorí pé bí mo ti ń wàásù ìyìnrere, kì í ṣe ohun tí mo lè máa ṣògo lè. Èmi kò tilẹ̀ le è ṣe é ní, kí a tilẹ̀ sọ pé mo fẹ́ kọ̀ ọ́ sílẹ̀. Ègbé ni fún mi tí mo bá kọ̀ láti wàásù ìyìnrere.