Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ministers: Should seek the salvation of their flock
Àwọn ẹsẹ nípa Should seek the salvation of their flock
Bí mo ṣè n gbìyànjú láti tẹ́ ẹnìkọ̀ọ̀kan lọ́rùn nínú gbogbo nǹkan tí mo bá ń ṣe láì wa ohun rere fún ara mi bí kò ṣe ti ènìyàn púpọ̀ kí ó lè ṣe é ṣe fún wọn láti le ní ìgbàlà.