Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ministers: Studious and meditative
Àwọn ẹsẹ nípa Studious and meditative
Títí èmi ó fi dé, máa fiyèsí kíkàwé àti ìgbaniníyànjú àti ìkọ́ni.
Máa fiyèsí nǹkan wọ̀nyí; fi ara rẹ fún wọn pátápátá; kí ìlọsíwájú rẹ lè hàn gbangba fún gbogbo ènìyàn.