Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mills: Often thrown down on enemies during sieges

2 ẹsẹ · 12 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Often thrown down on enemies during sieges

  1. obìnrin kan sọ ọmọ ọlọ lu Abimeleki lórí, ó sì fọ́ ọ ní agbárí.

  2. Ta ni ó pa Abimeleki ọmọ Jerubu-Beṣeti? Kì í ṣe obìnrin ni ó yí òkúta-ọlọ lù ú láti orí odi wá, tí ó sì kú ní Tebesi? Èéha ti rí tí ẹ̀yin fi súnmọ́ odi náà? Ìwọ yóò sì wí fún un pé, Uriah ìránṣẹ́ rẹ ará Hiti kú pẹ̀lú.’ ”