Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meekness: Urge, on their people 2 ẹsẹ · 29 abala Wá "Meekness" Gbogbo 109 General references 92 Christ set an example of 8 His teaching 8 David 5 Necessary to a Christian walk 3 A fruit of the Spirit 2 Are exalted 2 Instruct opposers with 2 Paul 2 Put on 2 Urge, on their people 2 A characteristic of wisdom 1 Answer for their hope with 1 Are beautified with salvation 1 Are guided and taught 1 Are preserved 1 Are richly provided for 1 Blessedness of 1 Exhibit, in conduct, &c 1 Follow after 1 Increase their joy 1 Moses 1 Precious in the sight of God 1 Receive the word of God with 1 Restore the erring with 1 Seek 1 Shall inherit the earth 1 Show to all men 1 The gospel to be preached to those who possess 1 Fi gbogbo 30 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Urge, on their people Titu 3:1Rán àwọn ènìyàn náà létí láti máa tẹríba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ. Kí wọn ṣe ìgbọ́ràn nígbà gbogbo, kí wọn sì múra fún iṣẹ́ rere gbogbo.Titu 3:2Wọn kò gbọdọ̀ sọ̀rọ̀ ẹnikẹ́ni ní ibi, kí wọn jẹ́ ẹni àlàáfíà àti ẹni pẹ̀lẹ́, kí wọn sì máa fi ìwà tútù gbogbo hàn sí gbogbo ènìyàn.