Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meekness: Restore the erring with

1 ẹsẹ · 29 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Restore the erring with

  1. Ará, bí a tilẹ̀ mú ènìyàn nínú ẹ̀ṣẹ̀ kan, kí ẹ̀yin tí í ṣe ti Ẹ̀mí mú irú ẹni bẹ́ẹ̀ bọ̀ sípò nínú ẹ̀mí ìwà tútù; kí ìwọ tìkára rẹ̀ máa kíyèsára, kí a má ba à dán ìwọ náà wò pẹ̀lú.