Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mashal: Called also Mishal and Misheal. A Levitical city in Asher.
Àwọn ẹsẹ nípa Called also Mishal and Misheal. A Levitical city in Asher.
Allameleki, Amadi, àti Miṣali. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ààlà náà dé Karmeli àti Ṣihori-Libinati.
Láti ara ẹ̀yà Aṣeri ni wọ́n ti fún wọn ní Miṣali, àti Abdoni,
Láti ẹ̀yà Aṣeri wọ́n gba Maṣali, Abdoni,