Mishal
A tún mọ̀ ọ́n sí: Misheal
33.0400, 35.1700 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Mishal
Allameleki, Amadi, àti Miṣali. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ààlà náà dé Karmeli àti Ṣihori-Libinati.
Láti ara ẹ̀yà Aṣeri ni wọ́n ti fún wọn ní Miṣali, àti Abdoni,