Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Hittites: Conquered by Joshua
Àwọn ẹsẹ nípa Conquered by Joshua
Nísinsin yìí, nígbà tí gbogbo ọba tó wà ní ìwọ̀-oòrùn Jordani gbọ́ nípa nǹkan wọ̀nyí, àwọn náà tí ó wà ní orí òkè àti àwọn tí ó wà ní ẹsẹ̀ òkè, àti gbogbo àwọn tí ó wà ní agbègbè Òkun Ńlá títí ó fi dé Lebanoni (àwọn ọba Hiti, Amori, Kenaani, Peresi, Hifi àti Jebusi)
wọ́n sì kó ara wọn jọ láti bá Joṣua àti Israẹli jagun.