Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Eleazer: 2. An inhabitant of Kirjath-Jearim who attended the ark

2 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. An inhabitant of Kirjath-Jearim who attended the ark

  1. Nígbà náà àwọn ará Kiriati-Jearimu wá, wọ́n sì gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa. Wọ́n gbé e lọ sí ilé Abinadabu lórí òkè, wọ́n sì ya Eleasari ọmọ rẹ̀ sí mímọ́ láti ṣọ́ àpótí ẹ̀rí Olúwa.

  2. Ó sì jẹ́ ní ìgbà pípẹ́, ogún ọdún ni àpótí ẹ̀rí Olúwa fi wà ní Kiriati-Jearimu. Gbogbo ilé Israẹli ṣọ̀fọ̀ wọ́n sì pohùnréré ẹkún sí Olúwa.