Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Benedictions: Levitical, forms of

4 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Levitical, forms of

  1. “Sọ fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Báyìí ni kí ẹ ṣe máa súre fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹ sọ fún wọn pé,

  2. “ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́.

  3. Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín.

  4. Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’