Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Benedictions: Divinely appointed
Àwọn ẹsẹ nípa Divinely appointed
“Sọ fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Báyìí ni kí ẹ ṣe máa súre fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹ sọ fún wọn pé,
“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́.
Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín.
Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’