Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ablution: Traditional forms of, not observed by Jesus
Àwọn ẹsẹ nípa Traditional forms of, not observed by Jesus
Nígbà tí Farisi náà sì rí i, ẹnu yà á nítorí tí kò kọ́kọ́ wẹ ọwọ́ kí ó tó jẹun.
Olúwa sì wí fún un pé, “Ẹ̀yin Farisi a máa ń fọ òde ago àti àwopọ̀kọ́: ṣùgbọ́n, inú yín kún fún ìwà búburú àti ìrẹ́jẹ.