Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zechariah: 8. A Levite, and father of Jahaziel
Àwọn ẹsẹ nípa 8. A Levite, and father of Jahaziel
Nígbà náà, ẹ̀mí Olúwa sì bà lé Jahasieli ọmọ Sekariah, ọmọ Benaiah, ọmọ Jeieli, ọmọ Mattaniah ọmọ Lefi àti ọmọ Asafu, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe dìde dúró láàrín àpéjọ ènìyàn.