Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zechariah: 16. A priest and temple musician

2 ẹsẹ · 16 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 16. A priest and temple musician

  1. pẹ̀lú àwọn àlùfáà díẹ̀ pẹ̀lú ìpè, pẹ̀lú u Sekariah ọmọ Jonatani, ọmọ Ṣemaiah, ọmọ Mattaniah, ọmọ Mikaiah, ọmọ Sakkuri, ọmọ Asafu,

  2. àti àwọn àlùfáà Eliakimu, Maaseiah, Miniamini, Mikaiah, Elioenai, Sekariah àti Hananiah pẹ̀lú àwọn ìpè wọn.