Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Worldly Amusements and Pleasures: Are likely to lead to greater evil

3 ẹsẹ · 21 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Are likely to lead to greater evil

  1. Ní ọjọ́ àsè ìrántí ọjọ́ ìbí Herodu, ọmọ Herodia obìnrin jó dáradára, ó sì tẹ́ Herodu lọ́run gidigidi.

  2. Nítorí náà ni ó ṣe fi ìbúra ṣe ìlérí láti fún un ní ohunkóhun ti ó bá béèrè fún.

  3. Pẹ̀lú ìmọ̀ràn láti ọ̀dọ̀ ìyá rẹ̀, ó béèrè pé, “Fún mi ni orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú àwopọ̀kọ́”.