Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wisdom: Of Ethan, Heman, Chalcol, and Darda
Àwọn ẹsẹ nípa Of Ethan, Heman, Chalcol, and Darda
Ó sì ní òye ju gbogbo ènìyàn lọ, ju Etani, ará Esra, àti Hemani àti Kalkoli, àti Darda àwọn ọmọ Maholi lọ. Òkìkí rẹ̀ sì kàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè yíká.