Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Winter: The Jews frequently had special houses for

2 ẹsẹ · 14 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The Jews frequently had special houses for

  1. Ó sì jẹ́ ìgbà òtútù nínú oṣù kẹsànán, ọba sì jókòó ní ẹ̀bá iná ààrò, iná náà sì ń jó ní iwájú rẹ̀.

  2. Èmi yóò wó ilé òtútù lulẹ̀ pẹ̀lú ilé ooru; ilé tí a fi eyín erin ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ yóò ṣègbé a ó sì pa ilé ńlá náà run,” ni Olúwa wí.