Phoenix
A tún mọ̀ ọ́n sí: Phenice
35.1900, 24.0800 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Phoenix
Àti nítorí pé èbúté náà kò rọrùn láti lo àkókò òtútù níbẹ̀, àwọn púpọ̀ sí dámọ̀ràn pé, kí a lọ kúrò níbẹ̀, bóyá wọn ó lè làkàkà dé Fonike, tí i ṣe èbúté Krete ti ó kọjú sí òsì ìwọ̀-oòrùn, àti ọ̀tún ìwọ̀-oòrùn, láti lo àkókò òtútù níbẹ̀.