Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wine: Intoxication from the use of wine
Àwọn ẹsẹ nípa Intoxication from the use of wine
Ọtí wáìnì tí ó ń mú ọkàn ènìyàn yọ̀, òróró láti mú ojú rẹ̀ tan, àti àkàrà láti ra ọkàn rẹ̀ padà.
Wọ́n ń jẹ oúnjẹ ìwà búburú wọ́n sì ń mu wáìnì ìwà ìkà.